Ewaede

Ewaede

Share

Ki asa ati ewa ede maa ba di oun igbagbe fun awon omo ka ro o jire, ni a se gbe iru eto bayi kale lati je ko je afani fun gbogbo awom omo bibi yoruba ati awon ololufe ede ati asa wa ja ke ja’do gbogbo agbanlaye. Igbagbo wa nipe nipa igbese ba won yi, asa ati ewa ede wa ki yi di oun igbagbe pelu ifowsowopo gbogbo wa. Iran yi, kiyio ku…be si ni igi kan ko le da ‘gbo se .Agba jo ‘wo la n fi so’ya.

Want your organization to be the top-listed Non Profit Organization in Osogbo?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Website

Address


Hon. Ad3
Osogbo
234