Asejere Group
It seeks to promote commerce in South West Nigeria, and encourages hard work and showcases successful entrepreneurs in the society.
05/05/2024
https://www.asejere.net/awon-eeyan-n-binu-si-sanwo-olu-nitori-basira-omo-wasiu-ayinde-to-yan-sipo/
Awọn eeyan n binu si Sanwo-Olu nitori Basira, ọmọ Wasiu Ayinde, to yan sipo - Àṣejèrè Awon eeyan ti won gbo pe Gomina Babajide Sanwo-Olu ti yan Basirat Damilola, omo gbajumo olorin fuji nni, King Wasiu Ayinde Marshall, ti gbogbo eeyan mo si KWAM1, si ipo oluranlowo pataki fun gomina lori eto igbafe nipinle Eko, ni won ti n se ayonuso lori oro naa, koda inu n binu won gidigidi ni, [.....
05/05/2024
https://www.asejere.net/ajo-lawma-fowo-ofin-mu-egberun-eeyan-lekoo/
Ajọ LAWMA fọwọ ofin mu ẹgbẹrun eeyan l'Ekoo - Àṣejèrè Ajo to n kole-kodoti nipinle Eko taa mo si LAWMA ti so o di mimo pe awon eeyan ti iye won le ni egberun kan lawon ti fi owo ofin mu nipinle Eko laarin odun kan soso. Komisanna to n sakoso eto ayika, Tokunbo Wahab lo se bayii soro yii fun awon oniroyin lose to […]
05/05/2024
https://www.asejere.net/idi-tawon-afobaje-ko-%e1%b9%a3e-ti-i-fi-olakulehin-je-olubadan-tile-ibadan/
Idi tawọn afọbajẹ ko ṣe ti i fi Ọlakulẹhin jẹ Olubadan tilẹ Ibadan - Àṣejèrè Bi nnkan kan ba wa to n di awọn ọmọ Ibadan ati gbogbo olugbe ilu nla naa lọwọ lati ni ọba tuntun, ọrọ ẹjọ kan to wa ni kootu lo n fa ipenija naa, ko si ti i jọ pe ẹjọ naa yoo kuro ni kootu kiakia bayii pẹlu bi awọn afọbajẹ ṣe n ta […]
05/05/2024
Arẹgbẹṣọla ki i ṣe ara wa lẹgbẹ oṣelu APC l'Ọṣun mọ – Adeleke - Àṣejèrè Kọmiṣanna tẹlẹ fun ọrọ ijọba ibilẹ ati oye jijẹ nipinlẹ Ọṣun, Ọmọọba Adebayọ Adeleke, ti sọ pe orukọ Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla ti kuro lara awọn gomina to ti inu ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) jade. Adeleke, ẹni ti gbogbo eeyan mọ ...
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Lagos
23401