Temitope alade
11/09/2024
Happy Birthday To ME TEMITOPE ALADE BABA OSHA 1❤️🥰
May All Irumole And Igbamole Be With Me
Ase! Ase!! Ase!!!
I Wish Myself Happy Birthday 🎂🎂🎂 Once Again.
Ifa lóni
Olúbó
Àsàbó
Òbòbòtiribò
Ifámojé-Kín-bósonù Lówó Re
Ifá Ní Edan Ni Mí
Edan Kiku
Ki Edan To Gbógbógbó,Ki Edan To Yóyóyó,Ki Edan Tó Kú Bi Okinni Aberé
Àwon Irá Ti Mo Bàsè Won Atikú Tán
Awon Ìwàrè-ìwàrè Ti Mo Básè Won Ati Gbòru Lobi Isu
Kíkú Tóyíkàn Mí Ojó Pé
Odù Kòkò Mejì,Won Ki Yíwon Kan Ara Won
Ewé Gbégbé Lóní Ki Mo Báwon Gbélé Ayé Pé Títií
Ifá Mómò Je Nkú Laitigbo
Roko-Roko Ki Romo Orósè Bi Omo-Eku Gbogbo
Owó Mi Wa Ba Ewé Elésó-ésó Oko
Èsò Ni Kinse Yun,Èsò Ni Kin Sebò
Èsò Ni Kinse Sùn,Èsò Ni Kin Sejí
Èjìogbè Kogbe Ibi Fo Lórí Mi
Òyèkú Méjì Koyeku Lórí Mi
Tóbá Yè Lórí Mi,Móyè Lori Òtá Mí...........
Ase
/!!!\
Happy birthday 🎂🎂🎂🎉🎉🎉 to me once again
EKALE EKU IJO META SI MEJI ADURA EMI ATI IWO TOBARI AMIIN SE YIO GBA LAGBA JALE
*ỌJỌ TI ODARÁ FUN IRAWO KAN-KAN LÁTI MA BỌ ORI*
Kii unse gbogbo eda ènìyàn nii o mọ pataki ojoru odara lati kaabo ori gẹgẹ bí irawo rẹ ṣe fẹ.
MOGBA LADURA orí èmi ati iwọ koni buru ọpọlọpọ awọn eniyan nii ounsise bíi erin tii ounjẹ ije ekute
Bíi ọrọ aiyé eda k'íbà nsba má nlọ dédé leyin Gbogbo igbiyanju yala ọsẹ wiwẹ ètùtù nigbigbe siwaju kii oto bọ Aje gbiyanju kii obo Orí rẹ
IRAWỌ OMI
Odara kii irawo Omi maa bo Ori ee nii Ojo Iboo ( Thursday)
Kii osi maase saara nii Ojo Aje (Monday)
IRAWO INÁ
Odarakii irawo Ina maa bo Ori ee nii Ojo Isegun ( Tuesday)
Kii osimase saara nii Ojo Eti ( Friday)
IRAWO AFẸFẸ
Odara kii irawo Afefe maa bo Ori ee nii Ojo Abameta (Saturday)
Kii osimase saara nii Ojo Iboo(Thursday)
IRAWO ERUPẸ
Odara fun irawo yii lati maa bo Ori ee nii Ojo Aiku ( Sunday)
Kii osimase saara nii Ojo ojoru (Wednesday)
TOBAFE MON NIPA INKANTI IRAWO RE FE LATIMA FI BO ELEDARE KONA RERE LEMALA KAN E, TABI SAARA TIWA MASE FUN IRAWO RE
IWO SHA TIPE EMI TEMITOPE ALADE BABA OSHA 1,SORI
PHONE NUMBER
08181222918 OR
09157512719 OR
08186829496
PELU IGBAGBO RE IRORUN NI ORO EMI ATI IWO MAJASI
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the practice
Telephone
Website
Address
Oladeji, Olukotun Street Off Ijegun Ikotun Road �
Lagos