Kini ife

Kini ife

Share

12/04/2024

OJUSE Ml (1)

Eku ojo meta gbogbo eyin tewa ninu Egbe yi ,
Ajose wa koni baje lagbara olohun .

Baba kan wa ,ti won n pe ni Baba Amoye , Baba yi je agbalagba ti o ni imo ati oye , gbogbo eniyan lo maa nwa Baba yi lati wa gba imoran lowo Baba yi lori oro idile won.

Ni irole ojo kan omo kekere kan waba Baba Amoye ,oni Baba amoye inu mi kodun rara lori oro awon obi mi mejeeji , Baba beere lowo omo yi pe kinlode?? Omo ni gbogbo igba ni awon obi mi mejeji jo ma nba ara won ja ninu ile, Baba beere wipe kin ni unkan na ti o ma nfa ija si arin awon mejeji ,Omo ni koye mi ooo, bai ni Baba amoye ati omo yi gbera odi ile awon obi re.

N igbati won yio fi dele awon obi omo yi ,oti to bi ago mejo ale , nigbati Baba wole bai ori ija nani won ba oko ati iyawo yi ti wonja unkan ti oko nso nipe ti won bati bioda ki o ma dana ounje lale yi, nkan ti iyawo nso nipe kosi ounje kankan ninu ile timo fe se lale yi, ,tori o fi owo kankan kale tiafi dana hmmmmm! Baba amoye pe oko pe ki o wa sugbon gege bi okunrin agidi po , koda Baba loun ,gbara ti Baba pe iyawo bai ni o da Baba loun .

Baba beere nkan ti o fa ti iyawo fini oun koni dana ounje, iyawo jeki o ye Baba lati ojo ti awon tise igbeyawo oko oun kosi igbakan fowo kale nile ri, ti owo siwa lowo re , orisirisi inawo ni oko oun ma nlo sugbon ko ranti ile ri lati ra nkan fun iyawo ati omo re , koda gbogbo eniyan lo ma n royin oko mi ni eyan dada nita sugbon kofi igbakan dun awa ninu ri , afi kieo dele ki o tun beere nkan ti yio je laifi owo sile nile,

Baba amoye ni se koju bayi lo , sugbon yo wumi ti wa ba tele oro mi timo fe so fun e loni yi, Baba ni lati dede asiko yi lo gbogbo nkan ti oko re bati beere bai ni ki o ma fun lai faja laifa ariwo ,
Obinrin yi beere lowo Baba pe se yio rorun fun oun lati se nkan yi bayi?? Baba amoye ni gbiyanju lati je ko rorun fun e lati se ,koda ki o se ewa kale ki oni rice loun fe je laifi owo kale gbiyanju lati se nkan ti o fe fun .
Bayi ni obinrin yi so fun Baba amoye pe moma gbiyanju lo

Want your business to be the top-listed Shop in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Website

Address


43, Town Planning Way, Ilupeju, Lagos.
Lagos
+234