Asejere
14/05/2024
Fiimu Funkẹ Akindele fidi rẹmi, ṣugbọn jagunjagun, Iya Rainbow gba awọọdu AMVCA - Àṣejèrè Bo ti ya gbajumo osere tiata nni, Funke Akindele ti gbogbo eeyan n pe ni Jenifa lenu pe o fidi remi, lawon ololufe re naa n yanu pe fiimu re, Tribe Called Judah ko gba awoodu kan kan nibi idije AMVCA to waye lopin ose to koja yii. Idije naa je eleeekewa iru re, to […]
14/05/2024
https://www.asejere.net/ajo-nff-ṣafihan-finidi-george-kooṣi-tuntun-fun-super-eagles/
Ajọ NFF ṣafihan Finidi George, kooṣi tuntun fun Super Eagles - Àṣejèrè Ajo to n sakoso egbe agbaboolu nile wa, NFF ti se afihan akonimoongba tuntun fun egbe agbaboolu ile wa, Super Eagles. Eni naa ni Finidi George. Bee o ba gbagbe, Finidi George ni igbakeji fun koosi Jose Peseiro, otyinbo to ko egbe naa lo si idije ile Afrika to waye laipe yii. Ilu Abuja ni […]
14/05/2024
https://www.asejere.net/sanwo-olu-fee-bere-ajoṣepo-nla-pelu-awon-alapata-lekoo/
Sanwo-Olu fẹẹ bẹrẹ ajọṣepọ nla pẹlu awọn alapata l'Ekoo - Àṣejèrè Gomina ipinle Eko maa bere ajosepo nla kan pelu awon alapata atawon eleran nipinle Eko, iso eran to wa ni Oko Oba ni Agege ni eto naa ti maa bere, bee ni won si tun maa sefilole awon ibuso ti won a ti maa ta eran naa. Eto yii waye lati toju awon eran ti […]
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Lagos
23401