BaBa ASEYORi
BABA ASEYORI TRADOMEDICAL HERITAGE
You can contact us for any of your health & spiritual problem such as: MENTAL DISSORDER,EPPYLEPSY,FIBROID,STROKE,PROGRESS IN BUSSINESS,LOVE SOAP,ETC....08038692880/08050673323
05/03/2026
OSE ATUDE OLOJO META
Wiwa Ninu Ide ni ki Eda ki o ma la Awon Alakala, ki Eda ki o ma sise sugbon ki o Mani Akojo, Tabi ki Iwo o pate oja kale ki o mari Eniyan ba Iwo na Oja re, koda owu alantakun kikoni Loju ni Gbogbo igba, Ara Ogun Aye kan ni.
Gbiyanju ki o bami SE ise yi, Odamiloju pe Gbogbo Ide Aye re yi o ja patapata ni.
OHUN TI AOWA
Obi Pupa 3
Kainkain Adeyba
Ose Dudu Eyikeyi
Agbon Odidi kan
BI AOSESE
Ao gun Awon obi yi papo mo Ose Dudu na, ao wa pin Ose na si ona meta.
LILO RE
Ojo meta ni ao fi we Ose yi.
Ago meta Osan ni ao si mabere wiwe Ise na.
Ao ma jo Omi Agbon Odidi kan sinu Omi iwe wa ti a bati Fe we Ise na, Kainkain otototo ni ao fi we Ise yi fun ojo meta na.
Ti o bari Ise yi SE ni asepe, Odamiloju pe wama fi ope fun olohun Eledumare oba nigbeyin ni.
Iwo na Bawa share re fun Anfani Awon Elomiran na.
Mogba ladura pe Omo Araye konifi Ide Owo won de wa tomtomo oo 🙏 🙏 🙏
Ire o!
03/03/2026
OGUN ABIWERE LOJO IKUNLE Pt2
(SUCCESSFUL BIRTH DELIVERY)
Eyi je ona ti Alaboyun lefi bi Omo ni Irorun ti won ba nrobi lasiko Ikunle, Olohun oba a si ma lo ni Sababi dada fun Gbogbo Obinrin Ti won bani idajuko Awon isoro kan Tabi Meji lakoko ti won ba nrobi lowo ti won yi o si bi Omo na Pelu Irorun,
Boya won ti so fun Iwo pe Ise Abe ni Iwo yi o fi bi Omo Inu re Latari pe Oju Ara ti e kere, Tabi Omo debu, Tabi isoro Miran.
koda, ti Ekeji Omo (Placenta) ti koba tete jade ti Omo siti jade, mofi olohun oba SE Eri, lesekese ni Ekeji Omo (Placenta) na yi o jade fun Ara re.
BI AO SESE
Ti Obinrin bade Ori Ikunle, ti Omo na ti nmu dada, Eni ki won o Baja Ewe Efinrin Tutu, ki won o fonu dada ki won o Wa gbe fun ki o maje ni Tutu bee, ki o simu Omi si
Motun fi Oba ti o da Ewe Ati Egbo se Eri, laarin iseju perete, Omo na yi o jabo pelu Irorun ni,
Ti i basije wipe Ekeji Omo na ni kotete jabo, Ti e ba gbiyanju re be, lesekese ni yi o jabo le pelu iyonda olohun oba.
Dakun Bawa share re fun Anfani Awon Elomiran na!
Mowa gba ladura fun Gbogbo Alaboyun TI won di Owo Ati Ese sinu, Olohun oba koni fi niyin Lara Lojo ikunle oo 🙏🙏🙏
Ire o!
26/02/2026
OSE ABI WERE LOJO IKUNLE
Ose yi wafun siso kale layo fun Gbogbo Alaboyun pata, paapa Julo TI Oyun na batile ni OSU mefa, odara ki Alaboyun ki o malo Ise yi.
Koda, Iwo Ti won ti so fun I pe Ise Abe ni won ma se fun o, mofi oba Ti o da Ewe Ati Egbo bura, o ma bi Omo na layo Ati Alaafia laiko sise abe kankan
Awon Ohun ti ao wa
EWE Abiwewe
Odidi atare 1
Ose Dudu Eyikeyi
LILO RE
Alaboyun na yi o Mafi fo Inu re Lati oke wasile,
Pelu ogo olohun oba Ti o seda Ewe Ati Egbo, Were lao Gbo.
Iwo na Bawa share re fun Anfani Awon Elomiran.
Gbogbo Alaboyun Tiwon diwo dise sinnu, lagbara olohun oba, ao gbo Ohun Iya Ati Tomo lashes Eledumare 🙏
Fun Ibere
08038692880
25/01/2026
Big thanks to
Princess Hafsa Lawal
for all of your support! Congrats for being top fans on a streak 🔥!
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the practice
Telephone
Website
Address
Lagos