Owuye

Owuye

Share

10/01/2023

Èèmọ, èyí ni bí àwọn ọmọ ilé ẹkọ gíga UNILORIN ṣe nsánnani lori ati rí Ọkọ lọ ile ìwé.

Asojukọ ìròyìn wa jẹ abọ pe, ni Tanke Òkè Odò laarọ yìí, awọn ọmọ ilẹ iwe to nlọ ile ìwé tu jáde, ṣugbọn ti wọn kò rí ọkọ wọ lọ ile ìwé.

Kini o fa, ṣe ti ọwọn gogo epo petiro ni, àbí Fara Babatunde idiagbon ti o nlọ lọwọ ni Tipper garage ni?

Want your business to be the top-listed Media Company in Ilorin?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Address


Ilorin
24140