BABA OSHA

BABA OSHA

Share

24/07/2022

ORi TOMA DADE INU AGOGO LOTIWA ORU LON TOMALO EJIGBALEKE INU AGOGO LOTIWA IDI TIO LO MOSAAJI INU AGOGO LOTIWA SE EWA RIPE OHUN GBOGBO LOWO ORI NI KI ORI JE KAGBO KATO ASE

08/07/2022

ASOSE TO DAJU
Itonno sawerepepe gbigbe Ewe Ola oa lo po pelu. ( ) ao ma fi si ori ahon ba eyan soro tabi fi gba nka lowo enia .
fun ibere pe mi tabi ko whatsab mi 08121244659.

07/07/2022

OSE OSE EYONU TODAJU. Ao yo igbin kan to pinnu dada ao gun ninu odo pelu epo obo ati imi ojo ao gun pomo ose agahin, ao ko sinu ike fufun olomori ao fi abere oporo bi pali kan gun ose lori ao de pa, ao gbe pamo fun ojo maarun, lehin ojo maarun odi wiwe
Lati owo oludasile egbe
Fun alaye e pe 08121244659, 08132712834.

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Badagry?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Website

Address


Ilogbo Eremi
Badagry
23401