Auto Mobile Engr

Auto Mobile Engr

Share

22/03/2024

Ẹ O ROJU AYE. BII...

Àwọn adigunjale ja wo inú ilé kan, wọn gba gbogbo owó àti dúkìá won.

Leyin náà, oga àwọn Igara olosa fi ibon owó ẹ lé baálé ilé náà lowo, ó pa a láṣẹ pé kó yín ìyàwó e nibon, tàbí kó koju ibon náà sí ara rẹ, kò yín mọ ara e.

Ọkùnrin náà gba ibon yìí, ó koju rẹ sì ìyàwó e, ó rò gbogbo ìfẹ́ tí ìyàwó rè bá lọ, àti gbogbo Iya ti wọn ti je papọ seyin, kò lè yín ibon náà, ó dá ibon yìí padà fún olórí ole náà. "Ẹ jọ̀wọ́ ẹ forí jin mi, èmi mi ò gbe". Oko ìyàwó fesi…

Olori àwọn odaran náà sì rọra gba ibon lowo rẹ, o fi ibon náà lè ìyàwó rè lowo, ó pa láṣẹ kò ṣe nkan ti wọn ni kí ọkọ ó ṣe to kò, ìyàwó náà gbà ibon lai besubegba, ó koju ibon náà sì agbari ọkọ rẹ, ó fa oko ibon ohun, ó di kéré, sugbon ko yìn, a ṣe ota kò sí nínú ibon náà.

Olori àwọn olosa náà gbà ibon lowo ìyàwó, kò wí nkankan, ó sowo sì àwọn ọmọ ẹ̀yìn kí àwọn máa lọ. Erin nìkan ni wọn rìn jáde. .

OJÚ WO NI EYIN FI WO.
1). Bó bá jẹ iwo ni ọkùnrin yìí, kini o ó ṣe fún ìyàwó bee???

2). Bó bá jẹ iwo ni ìyàwó, alaye wo ló fe se fún oko rè tí yóò fi gbe ara le e mo ???

3). Tí wón bá ní kò wapetu siru aawo yìí, kini o ó ṣe yanjú e

Want your business to be the top-listed Autos & Automotive Service in Sango Otta?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Website

Address

Sango Otta