Shepherd Media

Shepherd Media

Share

At Shepherd Media, We capture moments, tell stories, And give voice to the heart of Our Community || Through Our lens, We bring Clarity, Creativity, And Connection to every story. || your photojournalist in Oke-ogun, Oyo State.

Photos from Shepherd Media's post 25/05/2026

Interschool music competition organized by Sound of Joy voices Saki.

Ayorinde Mary Tosin Ayorinde Mayowa

25/05/2026

LATE REV'D KEHINDE OLAYIWOLA ISHOLA'S 10TH YEAR REMEMBRANCE

Dídùn nìrántí olódodo

Òní ló pé ọdún méwàá tí Olóògbé Àlùfáà Kehinde Olayiwola Ishola fi ayé yìí sílẹ̀.

Ọjọ́ rèé bí àná

Táa gba kámú fún Kò-ṣe-é-bá-wíjọ́ lórí ikú Wòlíì Ọlọ́run tòótọ́,

Akọni nínú iṣẹ́ Oluwa

Ògidì Abiyamọ

Bàbá tí wọ́n fi ń tọrọ

Báa sòótọ́, a ó kùú.

Báà sòtítọ́, a ó kùú.

Àlùfáà K.O. Ishola fi gbogbo ayé rẹ̀ sọ òdodo

Olóòótọ́ kìí lẹ́ní, ṣùgbọ́n kò ní sùn nípò ìká.

Títí di òní,

A sì ń sọ ipa rere tó o kó nínú ọgbà àjàrà Ọlọ́run, nínú ẹbí àti nínú ayé ọ̀kẹ́ àìmọye ènìyàn.

Iṣẹ́ rere rẹ sì ń fọhùn síbẹ̀.

Ó mà ṣe o, igi tó tọ́ kìí pẹ́ nígbó.

Ṣùgbọ́n a mú olódodo lọ ṣáájú ọjọ́ ibi.

Panipani kan ò sí níbìkan,
Àwáyéèkú ò sì ṣí.

Gbogbo wa la ó jíyìn iṣẹ́ ọwọ́ wa.

Ọdún mìíràn ti kọjá,

Wààwàà làkókò náà ń lọ

Ká bira wa bá a ṣe tán,

A le pè wá lọ́dún yìí

Kí Olódùmarè túnbọ̀ bá wa tẹ́ ọ sí afẹ́fẹ́ rere.

Àlùfáà K.O. Ishola,

Máa sinmi láyà Olùgbàlà,

Ó dòwúrọ̀ àjíǹde.

Níbi tí ìpinyà kò ní sí mọ́.

Ìdílé, ẹbí, ará, ọ̀rẹ́, aya, àwọn ọmọ àti ọmọ ọmọ ń selédè lẹ́yìn rẹ.







Ogo-Oluwa Baptist Church Saki

Photos from Shepherd Media's post 24/05/2026

BMC Secondary School, Saki, Oyo State with the third position during this year 2026 interschool competition organized by Sound of Joy voices Saki.

Want your business to be the top-listed Media Company in Saki?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Address

Saki
234