ORUN ANU

ORUN ANU

Share

Oru anu wa fun awon eyan ti won nidi ifowo sowopo lati ran won lowo fun adura .fun imoran tabi alaye lori page ,ete atejise si wa lori page bakannan eseun pupo.

10/12/2025

Eko gbogbo eniyan olorun , mogba ni adura fun wa loni pe bi odun Yi ti pari lo, emin emi ati e tofi de ori awon omo ati gbogbo afenifere , ani ba odun yi lo LORUKO JESU , odun ti awon wo yi ti bowa yi emi ati yin lama jo se . ire opin odun , ayo opin odun , ibukun opin odun, igbega opin odun., ki olorun ko le ami ati e lowo LORUKO JESU . ayo lao fi sodun ooo . for more prayers 🙏 Post this world and share it to your friends and family . thanks.

Want your business to be the top-listed Finance Company in Oyo?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Website

Address

Iyana Church Ibilade Street
Oyo
77121