Omo Odu

Omo Odu

Share

01/02/2025

Òhun réré tafẹ nilẹ yìí re
Àwa o fẹ Sharia court nilẹ k'aro Ajiire.

Ẹ jẹ o dúró níbi tan ti dasi nilẹ Arabu àti ilẹ Hausa.

Àwa o fẹ Sharia court nilẹ wà

24/12/2024

Èṣù and Satan are not equivalent. Èṣù is a complex, multifaceted force of balance and justice in Yoruba cosmology, while Satan is a figure associated with evil and opposition in Abrahamic religions.

Our Èṣù is never their devilish satan!

21/11/2024

Aku ojumọ ìrè eni ooo 👋👋👋
Ẹ gbọ nọ se lotitọ ni wipe 👎👎🤪🤪🤪

Visit TikTok to discover videos! 13/11/2024

Visit TikTok to discover videos! Watch, follow, and discover more trending content.

21/10/2024

Àní nkan ti bajẹ̀ jinọ latijọ to ti pẹ
Amọ nisẹyin Ilẹ k'aro Ajiire gbọdọ gba àtúnṣe réré.

20/10/2024

Gbogbo ẹ yin ẹlẹsin àjòjì nile k'aarọ aajiire abọgi bọpẹ le yín nọ ooo

Iwe bíbélì àti qurani yin igi nọ fiṣe

゚viralシ

20/10/2024

Iṣẹ pada já ni seh
Sọpe o ti cast 🎙️🎙️🎙️🎙️
irọ lásán
áràbù lẹfu ni gbogbo eee

Ę karo o 20/10/2024

Se ẹ tún ti gbọ túntún imiran
Itunmọ orukọ árábù yin re ooo
Ẹyin faridoh, fariyat, Fatimah.....
🤣🤣🤣🤣🤣🤣

Ę karo o

17/10/2024

Aṣiwère tabi òmùgọ a máà lẹkun sí nigba
Ọlọgbọn Èyán ba pirọrọ níbi ọrọ sísọ tàbi akitiyan

Fools multiply when wise men are silent.

07/10/2024

Ẹyìn ẹru k'ẹru yìí dá?
Ikan nínú yín ṣẹ se n da òtítọ́ mọ bọ ti jẹ wipe kòsí bí a bàá ṣe ṣe ebolo to tíì kòní rin igbẹ.

Ọrọ naa nrugbo bọ ooo

Want your public figure to be the top-listed Public Figure in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Culinary Team

Attire

Website

Address

Lafenwa
Lagos